Skip to content

Mi O So Wipe Mo Ma P’ara Mi Ti Buhari Ba Wa Le Laaye- Fayose

Fayose tii se Gomina ipinle Ekiti ti taku pe oun o so wipe oun yoo pa ara oun ti aare buhari ba pada wa si Nigeria laaye. Aare Buhari pada si Nigeria ni ojo abameta leyin meta le l’gorun ojo.

E TUN LE KA: Mo Ma Mu Buhari Larada Ti O Ba Wa Si Odo Mi- Satguru Maharaj Ji

 

Fayose’s Chief Press Secretary, Idowu Adelusi, so fun awon oniroyin pe oro pe oun ma pa ara oun ti buhari ba pada si nigeria laaye ko tenu gomina fayose jade pe awon egbe oselu All Progressives Congress, APC ni ipinle naa loo wa ni idi oro naa…..“Mr. Fayose never said he would commit suicide if the President returns to the country. It is the creation of the APC. It is their style to create such falsehood,”‎