Skip to content

Mi O Kin Sa Ere Boolu Ti O Wun Mi Lati Gba fun Nigeria- Victor Moses

Victor Moses ti wa siwasju lati so wipe irk ni o, oun o lki n sa aeon idije ti o wun oun lati gab fun Nigeria. Opo igba ni Moses o ti si ni ile lati ba aeon super eagles gab boolu, eye lo mu ki aeon ololufe super eagles wo pe Moses o fi taratara wa pelu Nigeria ati aeon super eagles. Moses ti o je moo agbaboolu fun Chelsea ti se laye kikun lori pro baa, o tenumo wipe oun wa nile ni igbakuugba fun orileede Nigeria ati aeon super eagles. Yes, everyone says that I select games. I have heard it myself,” the 26-year-old said. But it is what it is. I never run away from challenges. I love to play football, why would I run away from playing football? That is what we are meant to do. But people keep saying that I choose games for Nigeria … But I need to clear the air now that is not true. If I have got an injury, I have got an injury. Whenever I want to play for Nigeria, I must be 100 percent, I want to give everything. But if I have got an injury, I don’t want to force myself because I am going to look stupid on the pitch.”

Moses gba boolu ni ibi idije 2018 Fifa World cup qualifier ti super eagles ti gbe gba oroke lara camroon, ti super eagles na won ni 4-0 ti o si pelu awon ti o gba boolu wo inu awon.. Eyi waye leyin ti o pe Odun kan (1yr) ti o ti gba boolu gbeyin fun super eagles ni ibi ti won ti yege lara Algeria pelu 3-1 ni ibi idije World cup qualifier ti won gba ni Uyo.

Moses o si nibe nigba ti won gba idije ere pelu senegal ni march, ko de tun si ni ibe ni gbati won gba boolu pelu Corsica, Togo ati South Africa.