Bimbo Akinsanya ti o je obirin eleyinju ego ninu Yoruba movie industry ti jade lati we ara re mo lori iroyin ti o n kan kakaakiri wipe oun ti fe oko mercy aigbe, lanre gentry ri; O so wipe; “I did not even date him talk less of marrying him. Please they should let me be”.
Bimbo Akinsanya tun soro siwaju si lori oro igbeyawo ti e ti o tuka ati gbogbo iroyin ti n kan kiri pe bi omo odo ni o je ni ile okok e ki o to kuro nibe, o ni; “To put the record straight, I got married in 2014. I got separated from my husband in 2015 when my son was just three years old. I have since remained a single mother.”
Bimbo ti di Single Mother, ti o si ti pinu lati koju mo ise theatre ti on se tele.
E TUN LE KA: