Skip to content
  • Orin

MAYORKUN (@iammayorkun) FT. DAVIDO – BOBO

MAYORKUN FT. DAVIDO – BOBO

Leyin ti omo Toyin Adewale ti Aye mo si Mayorkun ti fi awon orin aladun dawalola; awon orin bii “Sade“, “Mama” and “Che Che“ ni o darapo mo oga re Davido lati gbe orin akoko ni odun 2018 kale ti o si pee ni “Bobo”.

Gege bi oye ti won fun Mayorkun iyen “Mayor of Lagos” o ti f’ede si awon eniyan ati ololufe re lenu wipe “Na Money be fine Bobo”

Killertunes ati Lush ni o pari orin naa ti Ayaworan Clarence Peters ni o ya fidio orin naa.

E DANLODU ORIN NAA NIBI KI E SI WO FIDIO RE LOKE ⇑⇑

DANLODU NIBI

Mayorkun-Davido-BOBO-video-720x540