Skip to content

Mark Zuckerberg Ati Iyawo Re Priscilla Bi Omo Keji

Oludasile ero abanidore Fcaebook, Mark Zukerberg ati iyawo re ti bi omo keji ti o je obirin. Zuckerberg fi inudidun re han lori ero abnidore re nigba ti o ko sibe pe inu oun ati iyawo oun dunlati ki omo obirin awon kaabo…. ‘Priscilla and I are so happy to welcome our daughter August!’

E TUN LE KA: Osere Bimbo Thomas Fi Aworan Omo Re Yangan

August Chan Zuckerberg ti won se bi ni aburo omo won akoko Maxima Chan

E ku orire o!!!!!!