Skip to content

LONI NI KO NI DOLA MMM TI SI PADA OOOO

Loni ni, Koni dola MMM ti o maa n se eto owo ti si ilekun Ero ayelujara won o.

Loni Ojo eti ni iroyin jade wipe won ti si Ero ayelujara naa ti a gbo wipe won fi n pese o owo ti awon eniyan amaa gba owo lati ibe naa. Ki odun 2016 to koja ni Awon ti o ni eto owo naa fun ipe sita wipe Awon fe ti Ero ayelujara won lati pada wa ni Osu sere (January) 2017 pelu erongba wipe awon yoo ti se ayipada si ibi ti won ti ku die kaato.

Opolopo eniyan lo ti n duro de ola ojo keerinla(14) January 2017 ti won so wipe yoo si pada , ki won le mo boya MMM ma si tabi ko ni si sugbon iyalenu lo je fun wa nigbati MMM kede ipadabo won ni ori Twitter loni ojo ketala(13) osu January odun 2017. Beeni won si fi si ori Ero ayelujara won wipe Awon ti de lakotun, ki awon eniyan mase beru.

Eka ikede ti won fi sita

MMM
<