Skip to content

Idi Ti Won Fi Le LOLA MARGARET Kuro Ni Ilu Oyibo

Osere Ori Itage; Arabirin Lola Margaret ti o je gbajumo ni idi ise tiata ni a gbo wipe o ti pada wa si Ilu Nigeria leyin ti awon Agbofinro Ilu US ti fi s’ewon lori Iwa jibiti.

Ileese Orisun rii gbo wipe Osere naa bo si panpe awon agbofinro leyin ti won ti f’oju si apo-ifowopamo re. Gege bi awon oyibo naa se so, Owo ti o wo inu akanti re je iye owo ti o n yanilenu bi o ti po to.

Ohun ti o mu ifura wa ni bi o se n gba owo naa kuro ninu ile-ifowopamo si.

Gege bi a se gbo, Osere naa ti pada wale leyin ti won ti lee kuro ni Ilu Oyibo.

E TUN LE KA: #ASIRI: Awon Nnkan Ti E Ko Mo Nipa MERCY Aigbe

Margaret-Lola-prison

Bi Ogbeni Kadiri se so:

“Lola Margaret ti ko lo si Ilu Ibadan nitori ituju nla ni wipe won le pada ti o je ibi ti o n gbe tele”. A si n reti ki Lola pada wa gege bii eni otun.

Arabirin Margaret je Oludari Sinima ati gbajumo ni awujo awon osere. Gege bi a ti mo, Sinima ‘Bisola Alan’ ni o gbe Lola jade lodun naa lohun.