#OrinTitun: Adekunle Gold X Simi – Ileri (Promise)

Leyin Ti iroyin igbeyawo ikoko won di ohun ti aiye gbo nipa re, Oko ati Iyawo Titun Naa, Adekunle Gold ati Simi gbe Orin titun kan jade

Iroyin Ti JADE Wipe ADEKUNLE GOLD Ati Simi Ṣe Eto MọmiNmọọ

Orin Naa ti won pe akole re ni Ileri, Je Orin ti Awon ololufe mejeeji na ti se ileri fun ara won

E wo Fidio Naa

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here