Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya

#IroyinLoriOrisun Awon aworan oye ti aya ti o kere julo ninu awon ayaba Alaafin Oyo ati awon omo re yaOlori ti o kere julo ninu awon ayaba Alaafin ti ilu oyo, Oba Lamidi Adeyemi ti oruko re n je Olori Badirat Olaitan Adeyemi ya aworan ti o lewa pelu awon omo'kunrin re mejeeji, ti won si jo wo aso kanna. Awon aworan naa wa loke. Ekunrere iroyin yii wa ni ori ero ayelujara wa ni @WWW.ORISUN.TV#News #Gist #Royalty #Queen #Beautifuul #Photos #OrisunTv #Orisun

Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya

Olori ti o kere julo ninu awon ayaba Alaafin ti ilu Oyo,Oba Lamidi Adeyemiti oruko re n je Olori Badirat Olaitan Adeyemi ya aworan ti o lewa pelu awon om’okunrinre mejeeji, ti won si ji wo aso kanna.
Olori Olaitan je arewa ninu awon aworan yii, ti o wo aso funfun lati oke de ile, oun ati awon omo re mejeeji.

E tun le ka: Olorin Fuji Alao Malaika Ra Ile Nla Si Lekki

Laipe yii ni Olori naa se gba kokoro oko ayo kele kan gege bi ebun lat’odo Kabiesi wa fun ti ojo ibi re ti o n bo lona, bi Olori naa se ma pe om’odun meji din logbon ni ose die si igba ti awa yi.

Awon aworan naa ree:

Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya

Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya

Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya

Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here