Skip to content

Lara Olubo, Ayinke Kujore ati Oga Orisun Ki Ijo Mo Le

Orisun ni agba, awa ni Oga. Ki ni idi ti a fi n so be? A ma n wi be nitori pe bi a ti n se nkan wa o yato si bi gbogbo ile ise se n se nkan won. Oga agba ile ise Orisun eyi ti o n se alakoso fun ile ise telifisan awon yibo ti won npe ni Isimbido da eto weje-wemu sile ni agbegbe ileese naa lati mo riri awon atokun eto wa. Ibi ayeye yi ni oga wa Kwame ti ki ijo mole pelu gbogbo awon atokun wa…

E TUN LE WO: Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

E wo ni bi yii>>