Skip to content

Kosi Aaye Fun Baba Isale Ninu Egbe Oselu APDA- National Chairman

Alaga Advanced Peoples Democratic Alliance (APDA), Malam Shittu Mohammed, ti so wipe egbe oselu awon o fi aye Kankan gba baba isale sugbon awon ma fun gbogbo omo egbe awon ni aaye lati se gbogbo nkan ti won ba le se.

Ogbeni Mohammed so eleyi ni ojo eti (Saturday) ni yola nigba ti o n baa won omo egbe naa soro.  O fi awon omo egbe re lokanbale wipe gbogbo won lo ni aaye gbaara lati dije fun ipo kip o labe egbe oselu naa. “We have no godfathers, we have no moneybags; ours is a level playing field for all members. We also believe in restructuring and devolution of power. I want to appeal to the National Assembly to revisit the issues”.

E TUN LE KA: Idi Ti Ijoba Se Da Ajo National Films & Video Censors Board (NFVSB)

Ninu oro ikinikaabo re, Alaga egeb nan i Ipinle Adamawa, Alhaji Umar Jada so wipe APDA ni omo egbe ti o po ninu ipinle naa nibi ti won ti ri egbe naa gegebi ajijagbara. Ogbeni jada so siwaju si wipe opo eeyan ni ilu adamawa ti bere sin i fi egbe oselu won sile lati dara po mo APDA.