Skip to content

Ko Si Nkankan Ti o Se Wizkid, Shaka Lara re wa

Olorin Ayo Balogun ti gbogbo eeyan mo si wizkid jade laipe yi lati so wipe ara oun oya ti o si gbegile awon international shows ti o ye ki o ti perform. Sugbon ojo wipe ara starboy wizkid ti ya bayi o nitoripe won ri olorin oun ti o n se ipalemo orin kiko ni Fela Shrine ni bi ojo meji seyin….

Ni ojo kerin osu September, WIzkid ko si ori ero abanidore twitter re leyin ti o soro wipe ara oun o ya wipe ti oun ba ku, oun ku gegebi legend, o si tun kede wipe oun ti sun tour oun siwaju atiwipe oun o ni le korin ni bi ayeye Made in America Festival ni Philadelphia.

Aworan wizkid ti o n korin ni Fela Shrine re:

wizkid-orisun

 

Fidio o ibi ti o tin korin naa re: