Ijoba Kwara ti so fun gbogbo ara ilu won wipe ko si aisan kayefi kankan ni ipinle na, gegebi iroyin lati owo commissioner fun ilera,Dr Atolagbe Alege.
Dr Alege so eyi di mimo ni ilorin nigba ti o n soro nipa iroyin ti on kan kakaakiri nipa aisan kayefi kan ni Oro-Ago in Ifelodun Local Government Area. Iroyin gba ilu kan wipe aisan kayefi kan gba agbegbe awon fulani kan ti awon eyan na n po nkan dudu ti won si n po eje ki won to je olohun nipe.
E TUN KA: Aregbesola Pe August 21 Ni Isese Day
Commisioner Alege so wipe ko si nkan ti o jo be ni ipinle kwara… “The ministry sees it as a rumour because we deployed a response team comprising of an epidemiologist, directors of public health and the disease surveillance response team”.
Commissioner tun so siwaju siwipe awon ti gbimopo pelu World Health Organisation lati ye agbegbe Oro-Ago wo ti won si so wipe awon o ri firi aisan kayefi kankanni agbegbe naa. won so siwaju si wipe aisan yellow fever, diarrhea and malaria wa ni agbegbe na.