A Ko Ni Igbagbo Pe Ijoba Nigeria Le Dabo Bo Wa
Asoju Orile-Ede America si Nigeria ati awon ti o n sise nibe ti ro awon ara ilu ati ile igbimo asofin agba lati fi itara si abo won gbogbo bi won ba n rin irinajo lori ofurufu lo si ita tabi awon ipinle miran ni Nigerian .
Ninu ate ti won fi ranse ni ojo Isegun, January 2017 ajo ti on ri si ajeji si orile-ede America ni Nigeria tun ran awon asoju ni Nigeria nipa awon ala ti awon apase Nigeria ti fa kale ati wipe ilera loro ati pe toju-tiye laparo fi n sori. Nitori na ki won ri pe gbogbo igba ni won ma mo ohun ti o n sele ni ibi i won ba wa.
Oro na jeyo latari awon ikedi pataki ti ijoba apapo fi sita ni ojo karun osu January, nipa papa ofurufu Nnamdi Azikiwe ni Abuja ti won fe ti pa fun igba die niori o nilo atunse ti o tun mo si pe oko ofurufu kankan ko ni le ba si ibe.
Ni awon akoko yi, gbogbo awon oko ofurufu to ba ye ko lo si Abuja ma dari si Papa Kaduna ti won ma dari gbogbo oko ofurufu ti o n bo lati oke-okun si Papa Kano,Lagos ati Port-Harcourt.
Nitori awon oko ofurufu ti o n lo si Kaduna ma po eyi le fa ijanba fun awon eniyan nitori awon odaran le fe fi akoko yen se ise ibi won. Ijoba de ti se ileri pe awon ma se eto abo ti o yananti bi olopa ologun ati bebelo fu Papa Ofurufu, ido reluwe, ati gbogbo opopona ti owo ipinle Kaduna ati abuja.
Sibe awon asoju America ko sai soro nipa awon ewu ti o le sele si won osise awon ni Portt-Harcourt ati Kaduna ti o je pe ija esin n fi ojojumo peleke.
Ninu ate ti won fi ranse, won so wipe gbogbo awon osise awon ati awon ebi won gbodo ri eri to daju lati America ki won to rin irinajo kankan lo si tabi kuro ni Kaduna, Kano ati Port-Harcourt ati irinajo lori popo lo si Abuja.
Won fi ye won pe awon ko ni igbagbo ninu ijoba lati ri pe ijanba kankan ko de ba awon ara ilu ki won to wa so awon ajeji ni Nigeria.
Nigbakana, won pase fun awon osise won pe won ko gbodo rin irinajo lo si awon Ipinle meta-din-logun eyi ti Edo, Kebbi,,Rivers ati Yobe wa lara won nitori awon apaniyan,, adigunjale and awon gbomogbomo ti won fi awon ipinle na se ibugbe.