Skip to content

KINI NKAN TI A N PE NI IGBAGBO?

Igbagbo lai si ise, asan ni o. Kini nkan ti a n pe ni igbagbo? Tani o ye ki a fi igbagbo wa si odo re? Tani o ye ki a ni igbagbo ninu e? ba wo lo se ye ki igbagbo wa jin to? igba wo lo ye ki a ni igbagbo di? se eyin ni igbagbo ninu olohun?

Gbogbo awon ibeere yi ni a dahun lori eto ojumo ire pelu atokun wa bolu adeseko ti o gbe wooli agba yi wa sori eto lati wa se alaye lori nkan ti a n pe ni igbagbo?