Skip to content

King Sunny Ade Pe 77yrs Ni Oni, E Ki Won Ku Orire

King Sunny Ade ti o n je Sunday Adeniyi je olorin omo ilu Nigeria, akorin, instrumentalist ati agba ominira fun orin ni Nigeria.

king_sunny_ade_orisun

Won bi King Sunny Ade ni 22 September 1946 si idile oba ni ipinle Ondo, ti King Sunny Ade si je okan ninu awon Ilu mooka ni idi orin. Lai pe yii, won fi King Sunny Ade, se asoju fun eto “Change Begins With Me” lati owo minister fun iroyin Lai Mohammed….

E TUN LE KA; E wo Bi Femi Adebayo Se Ki Iyawo Re Ku Ojo Ibi

KING-SUNNY-ADE-orisun

KING-SUNNY-ADE-orisun KING-SUNNY-ADE-orisun

E ku Ojo Ibi, Igba Odun Odun Kan Ni o….