Skip to content

Nnkan Iyalenu Ni Osinbajo Se Fun BUHARI Bi O Se Se OJO IBI

Nnkan Iyalenu Ni Osibajo Se Fun BUHARI Bi O Se Se OJO IBI

Igbakeji Are orile Ede Nigeria, Ogbeni Osinbajo ni ojo Aje ti o je Ojo Ibi Are orile Ede Nigeria iyen Muhammadu Buhari dari awon apapo awon gomina ipinle kaakakiri ati awon otonkulu ni Orile ede Nigeria lati lo be Buhari wo lojo ibi re ni Ile ti Ijoba gba fun-un.

Awon Ikinni orisirisi ni o wole si ori ago ati lori ero ayelujara fun Buhari lati fi kii ku oriire naa. Beeni, awon eniyan pataki lati inu egbe PDP (Peoples Democratic Party) ko gbeyin; won si fi asiko naa be Buhari ki o ma lo fun Saa miran (2nd Term)

Oluko Ti O N Ba Awon Omo Jeleosinmi L’ajosepo

Are ana, Ogbeni Goodluck Jonathan, Femi Fani-kayode pelu Ayodele Fayose naa wa lara awon ti o wa ni egbe APC ti o ki Buhari lojo naa ti o je Ojo ti o pe omo odun Marundinlogorin.

Awa naa n fi asiko yi ki won ku oriire naa.

Emi won a se pupo re laye ooo.

Vice President @ProfOsinbajo led a team of Governors and dignitaries to wish President @MBuhari a Happy 75th Birthday at the villa tonight.. #PMBAt75 pic.twitter.com/Aedq7IusmS

— Jubril A. Gawat (@Mr_JAGs) December 17, 2017