Skip to content

E Wo Iru ISINKU Ti Won Se Fun Aisha Abimbola (Omoge Campus) Ni Canada

E Wo Iru ISINKU Ti Won Se Fun Aisha Abimbola (Omoge Campus) Ni Canada

Won ti gbe Oloogbe Abimbola Aisha sin lana ojo ketadinlogun osu karun odun yii ni ite kekere kan ni oke okun laarin agbo eniyan ti ko po.

A sin arabinrin Aisha Abimbola ni ilana esin Musulumi ni agbegbe Toronto ni Ilu Canada ni bii agogo meji-abo osan ti o je ale ni orile ede Nigeria; iyen bii aago Mejo abo lale.

Die ninu awon ebi, ore ati ojulumo ni o pejo sibi eto isinku naa. Ore re timo-timo Lola Alao naa ko gbeyin nibi eto isinku naa.

Ohun ti a ri gbo ni pe Iku CANCER ninu omu(Breast Cancer) ni o pa Oloogbe naa.

E wo awon aworan ti o wa ni isale yii:

Oma Se O..Iku Ti O Pa Senator Nigeria Yii Ko Derun Rara

 

ORISUN-NEWS-aisha-abimbola-burial-6 ORISUN-NEWS-aisha-abimbola-burial-6 ORISUN-NEWS-aisha-abimbola-burial-6 ORISUN-NEWS-aisha-abimbola-burial-6 ORISUN-NEWS-aisha-abimbola-burial-6 ORISUN-NEWS-aisha-abimbola-burial-6