Odun Ijesu Ni Ilu Ogidi Lori Eto Isembaye

  ISEMBAYE

  Odun Ijesu Ni Ilu Ogidi Lori Eto Isembaye

  Odun Ijesu je odun ti a ma n se ni odoodun lati fi inu didun han pe Isu titun jade.
  Orisun je Telifisan ti o n ko omo ni ede ati asa pelu ise.
  Lori eto Isembaye, Iya Asa gbe wa lo si ilu kan ti won pe ni OGIDI lati fi oun ara ti a ba laye han.

  E wo fanran  yii ki e ko awon Asa wa.

   

   

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here