Skip to content

ISELE NLAA’BI TI O SELE NI ILU AMERICA LANA

Eniyan Merin ni won pa ati bii awon eniyan mejila ni o sese; Laarin won ni awon omode meji wa. Laaro Ana ojo isegun ni okunrin kan ti o ni ibon lowo n mu awon ti o fe pa kaakakiri awon ileewe ti o wa ni apa ariwa ni ilu Carlifornia ni America lati agbegbe miran.

Igbakeji Oga olopa ni agbegbe naa, Ogbeni Phil Johnson sofun awon akoroyin wipe Eni-ibi naa ti ku lowo ibon ti o gba gbogbo adugbo ti o bere ni aago mejo aaro (1600 GMT) ni ile kan ni Rancho Tehama Reserve ti o si gberu sii ni ileewe alakobere kan ni agbegbe naa. Ogbeni Phil so wipe kosi omo kekere kankan laarin awon oku ti won ri. O tesiwaju wipe awon ko ri idi kan tabi omiran ti isele naa se sele sugbon o gbe iranti Ija ti o ti sele ri laari awon ti o n gbe agbegbe naa.

America-shooting-mass-USA-Death-4dead

Ni ede geesi o so wipe;

“It was very clear at the onset that we had an individual that was randomly picking targets,”Johnston said at a news conference.

“This man was very, very intent on completing what he set out to do today.”

Iwe itan je ki a mo wipe eniyan bii 33,000 ni o n ku ni odoodun lowo iku ibon. Ti ida-meji ninu meta won maa n pa ara won ni gege bi Ajo ti o n mojuto Aarun ati aare ti so.

Awon idile awon ti oro naa kan ni itan Ilu Amerika pete-pero lati gbe Ileese ti o n se Ibon kan lo si ile ejo fun isele nla’bi naa.