ISE OWO NI ONA ABAYO FUN NIGERIA
Lotito gbogbo eniyan laye isin lo fe se ise ososu ti won ko si feran ise owo rara. Sugbon ti a ba wo gbogbo ohun ti o n sele, a ma ri pe ko si ise fun awon odo ti o setan altiile iwe giga nitori na ise ow se pataki ati koko .
Ki Nigeria le dagba soke bi awon orile-ede to ku ki osi ati ise si di ohun igbagbe, awon odo wa lati bere sin ni u ise owo ni okun-kun-dun.
Arabinrin Lola Akande ti o je comissioner ile-ise tohun ri si oro awon obinrin ati kiko ise owo ni ipinle Eko lo fi eyi se mimo nibi ayeye ikosegboye ise owo ti ile-tohun rise awon obinrin seto fun awon ara agbegbe Ikorodu.