Skip to content

Iroyin Ti JADE Wipe ADEKUNLE GOLD Ati Simi Ṣe Eto MọmiNmọọ

Iroyin Ti JADE Wipe ADEKUNLE GOLD Ati Simi Ṣe Eto MọmiNmọọ

Gẹgẹ bi a ti rii gbọ, Adekunle Gold ati olohun ṣuga ti gbe ibaṣepọ wọn de ibi giga ti wọn si ṣe eto mọminmọọ ni opin ọsẹ ti o kọja yii.
Gẹgẹ bi Ileeṣẹ iroyin TheNET ṣe sọ, awọn mejeeji se diẹ lara eto igbeyawo eyi ti o maa n fi idile iyawo mọ ti ọkọ, bẹẹni awọn ẹbi, ara ati ọrẹ awọn ilumọọka olorin naa ni o peju-pesẹ si ibi ifinihan naa ni ilu eko sugbọn wo ko fi aaye gba ẹnikan kan lati ya aworan tabi gbe iroyin naa sori afẹfẹ.
Ni ori ẹrọ alatagba Instagram ni ileeṣẹ iroyin naa ti gbe iroyin naa jade pẹlu ede gẹẹsi ti o ka bayii:

“Did you guys hear that Simi and Adekunle Gold are now engaged? The two had a low key introduction ceremony this past weekend. ??????
.. It was attended by only their family and close friends, and photos were not allowed to be taken. Wish them all the best guys! And when you see photos, remember we told you first” ????❤️❤️❤️❤️
They are now accepting hashtag suggestions oh

Simi-and-Adekunle-Gold-engaged-hold-wedding-introduction-nigezie-xtreme