Skip to content

#IROYIN: Rihanna Pe Baba Re Lejo Fun Esun Jibiti

Arabirin Olorin Agbaye Ti A Mo Si Rihanna Ni A Gbo Wipe O Fi Esun Jibiti Kan Baba Re; O Si Ti Pe Ni Ejo.

Rihanna Ti Pe Baba Re Lejo Ni Ilu California, Wipe Baba Oun Fi Oruko Idile won Pa Owo Si Apo ara re. Oruko eyi ti oun ti jiya lati so di ilumooka.

Obasanjo Tabi Baba’sale Kan Ko Ran Mi Ni Idije Fun Ipo Aare Odun 2019 – LAMIDO

Rihanna Ti O Je Omo Ogbon Odun pelu apeja-oruko re Je Robyn Rihanna Fenty, Fi Esun Naa Kan Baba Re Ronald Fenty ati eni ti won jo n s’owo po; iyen Moses Joktan Perkins. O tesiwaju lati jewo Wipe Awon Okunrin Mejeeji Na Ti Fi Ona aito fa oruko oun mo Ile Ise Won “Fenty Entertainment” ti o si je wipe oun ko ni ibase kankan pelu ileese naa.

#OrinTitun: ZLATAN (@zlatan_ibile) – ZANKU : LEGWORK

Won Si Ti Fe fi Ona Alumokoroyin se agbekale ayeye Orin-ita-gbangba ni oruko oun lai gba ase lowo oun.

Bi A Ti Nsoro Bayii, A ko tii Gbo Ohun kankan Lati enu Awon Okunrin Mejeeji ti a f’esun kan Naa.

Tags: