Skip to content

Iroyin: Ito Suga Ati Okunfa Re

Ito Suga Ati Okunfa Re

Ito Suga je aisan ti o ma n de ba eni, nigba ti suga (glucose) ba ti poju ni nu eje. Ara nilo suga ni tori oun ni o fun ni ni agbara. Sugbon ti o ba ti poju o le wu fun ago ara. Oun ti o n se okunfa a poju glucose yi ni ara ni, oun ti a n je ati igbe aye ti a n gbe. Eya kan wa ninu ara wa ti won pe ni Amo, iyen ni “Pancreas”. Amo yi ni o n pese oun kan ti won pe ni insulin. E wo fanran yii fun ekun rere iroyin yii.

IDANI LEKO LORI ITO SUGA

YouTube player
Tags: