Skip to content

IROYIN: IDANILEKO LORI ITO SUGA (DIABETES)

ITO SUGAR; ORO AKOSO

Ito suga je okan laarin awon aarun to wopo laarin awujo wa. Aarun naa tumo si wipe suga (glucose) po ju ni ara. Lotito lo je wipe a nilo suga lara wa, sugbon apoju re ni ko dara rara.

E TUN KA ELEYI:    AARE BUHARI SE AYEYE OJO IBI FUN OMO-OMO RE

OHUN TO N FA ITO SUGA

Gege bi awon onimo isegun se wi, eya kan wa lara to n je Amo. Amo yii lo so suga ti a n je di okun ninu ara wa. Amo yii ma se eleyi nipa sisun oje ara to n je “Insulin”.

Orisirisi ito suga lo wa. Fun ekun rere, e wo fonran to wa ni isale yi:

YouTube player