Skip to content

Ipinle To Ni Iwa Jegudujera Ju Ni Nigeria

Ajo Statistician General of the Federation ati oludari Nigerian National Bureau of Statistics, Dr Yemi Kale ti fi esi survey ti won se lori iwa jegudujera ni orile ede nigeria. Gegebi iwadi won se lo, awon riba ti won fun awon osise ijoba lo poju si south west ati north west. awon ilu ti o wa ni southwest ni….

1. Lagos

2. Ogun

3. Osun

4. Oyo

5. Ekiti

6. Ondo

Ni  north-west, awon ilu ti iwa jegudujera won po ni :

7. Kaduna

8. Zamfara

9. Kano

10. Katsina

11. Jigawa

12. Kebbi

13. Sokoto

E TUN KA: Mo Ma Mu Buhari Larada Ti O Ba Wa Si Odo Mi- Satguru Maharaj Ji

Siwaju si, ni aarin June 2015 ati 2016, aawon ara ilu nigeria fi N82 million se riba ni igbimo osise ijoba, won si fi ye wa wipe 52% awon omo nigeria ni o fun osise ijoba ni riba ti won ba bawon pade. Ninu iwadi won, awon olopa  ni o n gba riba ju ti o si je wipe awon nurses ni o n gba riba to kere ju