Skip to content

Ipinle Kaduna Ti Kede Gbigba Awon Oluko 25,000 Fun Odun T’on Bo

Ipinle Kaduna Ti Kede Gbigba Awon Oluko 25,000 Fun Odun T’on Bo

Ijoba Ipinle Kaduna ti n gbe igbese lori wiwa ise fun awon ti o wa ise Oluko ni ipinle naa kaakakiri awon ile eko alakobere ti Ijoba.

Ajo ti o n bojuto oro Eko ni ipinle Kaduna iyen (SUBEB- Universal Basic Education Board) so wipe idanwo fun awon oluko ti o fe wole naa yoo bere ni ojo ru December 20th odun 2017. Ninu atejade ti Nasiru Umar filele ni Ojo aje, o so wipe Idanwo naa yoo waye ni awon agbegbe kookan ti awon ti yan ni ijoba-ibile metalelogun ni ipinle naa ni dede agogo mewa aaro.

Ogbeni Nasiru fun Ajo SUBEB so wipe awon ti o fe se idanwo naa yoo ko Idanwo naa ni agbegbe ti won n gbe; beeni awon ti o fi oruko sile lori ero ayelujara ati awon ti o wa lati ipinle miran yoo ko idanwo naa ni ibi-idanwo ti o sunmo won.

Teachers-oluko-teaching-kaduna-Training-Tuition-Tutorial-Study-Centres-in-Nigeria-Lagos-Abuja-Port-Harcourt-Ibadan-Abeokuta

Ninu atejade ti a ri gba, won ran awon ti o fe se idanwo naa leti wipe ki won mu nnkan ti won yoo fi kowe ati aworan passport meji ti ko pe ti won ti ya ni aago mejo aaro fun ayewo finnifinni.

Eyi ni awon Ibi ti SUBEB ti yan fun idanwo naa:

 1. B/Gwari 3 SSS B/Gwari, GGSS Bagoma1, GSS B/Gwari 1
 2. Chikun 16 GSS S/Tasha 3, GSS Kujama2, GSS Narayi 2, GSS U/Romi 1, GSS TV3, LGEA U/Romi 1, GSS U/Boro 3 and LGEA U/Maichibi 1.
 3.  Giwa 3 GSS Yakawada 1, GSS Shika 1 and GSS Giwa 1
 4. Igabi 5 GSS Rigachikun 1&2, GSS Afaka 1, GSS Rigasa 1 and GSS Jaji 1 5. Ikara 3 GSS Ikara 3
 5. Ikara 3 GSS Ikara 3
 6. Jaba 2 GSS Kwoi and GSS Ngamsham Kwoi
 7. Jema’a 7 GGSS Kafanchan 1&2, GSS Kafanchan 1&2, GSS Zikpak 2 and GSS U/Fari 1
 8. Kachia 5 GSS Kachia 2, GSS Gumel 1 and GSS Kachia Urban 1
 9. K/North 11 GSS Kawo 1, Rimi College 2, GGSS Independence Way 1, GGSS Kabala Costain 1, GSS Kawo 1, GGSS Dalet 1, GSS U/Sarki 1 and GSS U/Rimi, GSS Doka Boys 1, GGSS Doka Girls 1
 10. K/South 16 QAC 3, GGSS Makera 1, GGSS Kudendan 2, LGEA Kudendan 1, LGEA Makera 2 and LGEA Baban Dodo 2, GGSS Maimuna Gwarzo 1, GGSS U/Muazau1, GSS Barnawa 1
 11. Kagarko 5 GSS Kagarko 2, GSS Dogon Kurmin 1, and GSS Kubacha 2
 12. Kajuru 2 GTC Kajuru 2, GSS Kajuru
 13. Kaura 5 GSS Manchok 2, GC Kagoro 1, and GS Kagoro 2
 14. Kauru 3 GSS Kauru, GSS Pambeguwa and GSS Kwassam
 15. Kubau 3 GSS Anchau Takalafiya, GSS Pambeguwa and GSS Dusten Wai
 16. Kudan 1 GSS Hunkuyi 17. Lere 5 GSS Lere2, GSS Sminaka 2, and GSS Ungwan Bawa 1