Wednesday, July 15, 2020

Awon Omo Ganfe Kan Sekupa Omobirin Kan Ni Ipinle Oyo |...

Awon Omo ganfe ni Iroyin de eti igbo wa ni amohunmaworan orisun ni o sekupa Omobirin kan ni ipinle Oyo. Iroyin Lekunrere Re. 

Aare OnaKakanfo Ba Awon Omode Soro Lati Je Olododo Ninu Ohun...

Aare Onakakanfo Ile Yoruba "Gani  Adams" Ba Awon Omode Soro lati je olododo ninu ohun gbogbo ti won nse, O si ba awon Obi...

Egbe Oselu PDP Tako Iroyin To Sowipe Won Ni Ibasepo Pelu...

Egbe Oselu PDP ti tako Iroyin ti o sowipe won ni Ibasepo pelu igbakeji gomina ipinle Ondo. Iroyin naa Lekunrere 

Iwoye Bi Ode Se Ri Bi Awon Osise Se Wole Pada...

Awon Eniyan ti pada senu ise ni Ojo kerin osu karun, Lati Amohunmaworan orisun, a jade lati wo bi igboro se ri. E wo bi...

COVID-19: Central Bank Of Nigeria Dekun Awon Ile Ifowopamo Ni Dida...

Ile Ifowopamo Agba, CBN ti dekun awon ile ifowopamo ti o npinu lati da awon osise duro lenu ise lori arun Covid 19 Iroyin Lekunrere 

COVID-19: Ijoba Ipinle Osun Se Akosile Titun Lori Arun Corona

Ijoba Ipinle Osun ti Se Akosile Tuntun lori arun eyi ti o gba ode kan, arun yii ti a mo si COVID-19 ni  ipinle...

Ẹṣe Alabapin Ninu Iroyin Wa

Lati Gba Awọn Iroyin Wa Ninu Imeeli Yin