Skip to content

Idi Ti Ile Ejo Fi So Wipe Ki Won ARREST Omo Bola IGE

Idi Ti Ile Ejo Fi So Wipe Ki Won ARREST Omo Bola IGE

Ile Igbimo asofin ti ilu Osun ti ja iwe lati ti omo Bola Ige mole fun esun ti won fi kan-an. Ogbeni Muyiwa; Iyen Muyiwa Ige ti o je Komisona fun Lands, ati physical planning ati idagbasoke Ilu nla ni Ipinle naa.

Hmmmm Oro ile kan ni o sele ti o n fi awon ara adugbo lokan ni ilu Ilobu ti won si pe Komisona naa ti ko si je ipe naa.

Iroyin jade lati ileese Osun State Broadcasting Corporation (OSBC) wipe ki Komisona Muyiwa Ige je ipe naa bi o ti jade lati enu awon amofin-sofin naa.

Okan lara awon asofin naa bebe wipe ki a ma se afihan oruko oun so wipe awon pe Ige ni ori ero asoro-magbesi (Radio) ni ojo isegun ti o koja wipe ki o wa jejo niwaju awon sugbon awon ko rii lati igba naa. Gege bi asofin naa ti so, o wipe Ige nikan ko ni awon pe ko wa jejo; akapo teleri fun Ministry naa yoo wa jejo.

E Wo Nnkan Ti Olopa Yii Se Ti O Fi Mu Emi Onimo Yi Lo Nilu Ekiti

Ninu oro ti o so, o wipe:

Aminu-Waziri-Tambuwal-court-nigezie-tv-orisun-yoruba-news

“It is true but the invitation was aired on OSBC on Tuesday and if he (Ige) was not in the state, he might not have heard that he was invited.”

“The PS also did not come but he called to notify us that he would not be available today (Wednesday). We didn’t receive any call from Muyiwa until evening time when he called and told us that he was not aware of the invitation. He was not even accused of stealing anything so, I think he would come on Monday or so.”

Nigba ti a pe Ige, oniroyin wa jabo funwa lati ero alagbeka wipe o ni oun ko mo nipa Ipe lati wa jejo naa.

Ogbeni Muyiwa Ige ti o n jaya nigba ti o gbo wipe won fe mu oun so wipe Oun ko gbo ooooooo Ninu oro ti o so o wipe, oun kan gbo ninu iroyin, kosi iwe kankan ti o ranse si oun ki oun wa jejo.

Gege bi o ti so ni exe Oyinbo;  “I just heard the same way you heard it. Nobody invited me. I was even in Osun State till 7pm on Tuesday.”