Skip to content

ILARA LO SO MI DI ALAPA KAN-SAM GLORIOUS

Sam Glorious je elere itage christiani ti o ma n se ere theatre nipa eko olorun pelu erin ni awon ile ijosin kakaakiri. Ere theatre sam glorious farape iru eyi ti Alfa Sule ma n se.

Sam Glorious ati Atabatubu ni won jo wa lori eto Ojumo Ire ti won si jo fi oro jomitoro ero lori bi sam glorious drama school se bere ati orisirisi nkan ti o sele ni ile aiye sam glorious…. E ba wa ka lo….

E TUN LE KA: Mo FI Orin Sile Fun Igba Die Nitori Oko Mi- Busola Oke

E TUN LE WO ERE SAM GLORIOUS: