Skip to content

Oma Se O..Iku Ti O Pa Senator Nigeria Yii Ko Derun Rara

Oma Se O..Iku Ti O Pa Senator Nigeria Yii Ko Derun Rara

Sineto Ali Wakili ti o n s’oju Iha guusu ni ipinle Bauchi ni iroyin iku re ba wa lokan je gidigaan. Ogbeni Wakili ku ni iye omo odun mejidinlogota.

Ko je b a se rii gbo, Ali Wakili ku iku ojiji leyin ti Okan duro lojiji (Heart Attack). Gege bi awon ebi Ali se so, Ni agbegbe Gwarimpa ni o ti gb’ekuru je lowo ebora laaro ojo abameta ti o koja ti won si sare gbe lo ile-iwosan sugbon epa o boro mo; bi awon Ile-iwosan naa (Viewpoint Hospital) se kede iku re.

Titi di ojo iku Mr Wakili ni o je Alaga fun awon igbimo fun kikoju ise (Poverty Alleviation).

Ki Oba Alaanu bawa te won si afefe rere. (Amin).