Skip to content

Ijoba Osun Pese Eran 648 Fun Tita Fun Odun Ileya

Ijoba ipinle osun ti pinu lati pese eran 648 fun odun ileya ti o n bo lona. Eton a ti won pe ni ‘O’RAM pelu ajosepolati owo Selema Oloba Ranch, Iwo ti sin eran bolojo ni aarin osu meji. Gegebi oludari Selema Oloba Ranch, Sola Omidiran se so, awon eran 648 ti won sin ni ibudo eran won yi wa lati orisirisi agbegbe ipinle ni North. Won se alaye siwaju si wipe

“In a bid to enhance our marketing strategies, we have gone to partner with varying online stores with our website, or online sites like Jumia, Ebeano Supermaket, Red and Green Butchery and Lekki Farms. With all what we are doing, we can assure you that we will give you value for money. There will be nowhere else you will find rams that are of good quality like these other than the Selema Farms. We have animals in four different categories that are going for different prices that are for sale. We have the Bronze category of about 25-30kg for about N45,000; the Silva Category of 31-36kg for N60,000; Gold category of 37-43kg for N70,000 and the Platinum of 44-50kg for N80,000.”

 E TUN KA: Nje O Dara Ki Eniyan Fi ISE Ijoba Sile Se ISE ORIN?

Yato si eran, ogbeni omidina so wipe awon ni ewure, maalu, tomatoes, alubosa, atarodo ati orisirisi oun ogbin. Ajo O’Rams ati Livestock project je ara awon ise Osun Rural Enterprise and Agricultural Programme O’REAP, ti o je okan gboogi ninu ijoba Governor Rauf Aregbesola.