Skip to content

Ijoba Eko Setan Lati Palemo Abe Bridge Ojuelegba ati Ikeja

Lati tun gbogbo awon idiko ti o wa ninu ipinle eko se, ijoba ipinle eko ti da ajo kan sile lati ri wipe awon idiko ti o leto ki o wa ni abe bridge ojuelegba ati ikeja poora.

Alaga ajo yi, Olayinka Egbeyemi, so wipe ajo na ma bere si mu ise won ni sie ni ojo Aje, September 11, 2017 leyin ti wakati Meji din laadota (48hrs) ti won fun awon ti oro na kan lati kuro ni abe bridge oun ba pe. Egbeyemi tun fi kun wipe owo sikun awon osise ajo yi ma tea won awako ti o se nko ti o to ni abe bridge oun…  “All these illegal motorists engaging in commercial activities around Ojuelegba and Ikeja by Ipodo Market, Awolowo Way, have been served a ‘Quit Notice’ on Saturday, September 9, 2017, to vacate under the bridges immediately. Activities of these illegal motor parks are contributing to the traffic gridlock across the state. No responsible and responsive government will tolerate criminal activities being carried out by hoodlums and miscreants around these illegal parks.”

Ogbeni Egbeyemi fi ikilo pe enikeni ti o ba duro si ona oun ati awon omo ajo oun ti awon ba n sise awon ma fi oju ko ofin, ki won si gbo si awon lenu lati gbe oko won kuro ni idiko naa.