Skip to content

IJOBA Buhari Ti Pofo Leyin Gbogbo Ileri Ti O Ti Se – Bishop Oyedepo

IJOBA Buhari Ti Pofo Leyin Gbogbo Ileri Ti O Ti Se – Bishop Oyedepo

Oludasile ati adari Ijo nla WINNERS ti gbogbo aye mo si Living Faith Church, Bisoopu Oyedepo David ti se apejuwe Are Muhammadu Buhari gege bi Olofo ti o p’ofo leyin gbogbo ileri ti o ti se ki o to wole si ipo Aare naa.

Laise’nuku, Oyedepo so wipe Ijoba apapo jebi bi won ko se wa nnkan se si oro awon daran-daran ti o paniyan kiri.

Ni Ojo kejilelogun osu kerin ti a wa yii ni Bisoopu naa so ni ede geesi gege bi a ti rii gba wipe:

“Can I tell you my anger against this government? No feeling for human lives. You can’t be destroying the work of my father and I will be happy with you. You know what God said? I am angry with the wicked everyday.

“Talk is cheap! You see where change brought us today since 2015? The changest change!

“1 naira will be one dollar. Fuel will be sold at 45 naira. Any responsible government will bring power in 3 months.

“If you bring the scoresheet out, it’s 0%. Do you want change? Work it out ! You better wake up so you don’t suffer the Nigerian kind of change. Theoretical change.

“3 refineries working! (They must be) located in space. Defending killers! God’s judgement will hit!

“If you are happy with what God is angry with, you are ungodly.

“Those who have made others childless, wifeless, husbandless, so shall they become! Do you pray for Armed Robbers? Evil shall not prevail in Nigeria!”

Are Buhari laipe yii so wipe awon Odo orile ede nigeria ya Ole, oun ni o faa ti won ko fi ni ise lapa ni ibi ipade awon oloja ti commonwealth ni Ojoru ojo kejidinlogun osun kerin odun yii.

Oludamoran fun Buhari lori Iroyin ati atejade iyen Ogbeni FEMI ADESINA ni o f’aso asiri boo pelu atejade t’o gbe sita wipe oga oun Buhari so oro naa pelu ohun agba sugbon awon eni-ibi ni o gbe oro naa gba’gi lati fi te ara won lorun.