Ijoba Aare Mohammed Buhari ti gbese kuro lori Unified Tertiary Matriculation Examination (UTME) ti won n se lati gba akeko wole si ile iwe giga. Minister fun eto eko, Malam Adamu Adamu so elyi di mimo ni Abuja ni ojo isegun Tuesday, August 22. Mallam Adamu so wipe ipinnu lati gbegile sise post utme je asise ati wipe idi ti won fi gbegile o seyin iwa ajebanu ninu eto eko. Mallam Adamu so wipe ile eko giga Kankan o gbodo gba owo asanwole Egberun Meji #2000 lowo akeko lati se idanwo post utme wipe ofe ni o gbodo je lain i iwa ajebanu ninu.