Skip to content

Ijoba Apapo Ti Pase Ki Won ti Ibi Ipago Awon Agunbaniro Kakiri Orile Ede Nigeria | Iroyin 18th March

Ijoba Apapo Orile ede Nigeria ti Pase Ki won ti gbogbo ibi ipago awon Agunbaniro kakiri Orile Ede Naa nitori ifoya ati Aabo fun awon Agunbaniro lori Igbodekan Arun Corona.

 

Ekunrere Iroyin naa Re.