Skip to content

IJOBA APAPO PE FRIDAY ATI MONDAY NI ISINMI FUN ODUN ILEYA

Ijoba apapo ti kede pe ojo jimoh Friday,sept 1 ati ojo aje Monday,sept 4 gege bi ojo isinmi lati fi se ajoyo odun ileya. Minister of Interior, retired Lt.-Gen. Abdulrahman Danbazau‎, lo so oro yi fun ijoba apapo ni ojo aje ni Abuja. Dr Rufai Attahiru, ti o n mojuto office permanent secretary ni ministry na fi onte lu oro nan i Abuja.

E TUN LE KA: Ijoba Osun Pese Eran 648 Fun Tita Fun Odun Ileya

Minister fi eyi be awon musulumi ati gbogbo omo Nigeria lati fi ayeye yi gbadura fun isokan,ifokanbale, ilosiwaju ati idurodede democracy orileede wa. O tun pea won Nigerians pe ki won pa owo po pelu ijoba president muhammadu buhari lati gbe orileede wa ga.