Skip to content

Iheanacho Omo Wa Gba Ami Eye Agbaboolu Ti CAF Ni Africa

Iheanacho je Agbaboolu ti o kara si ise owo re. Lale ana nibi ayeye CAF Awards, Oun ati Akegbe e ti oruko re nje Alex Iwobi.

Iwobi Je agbaboolu fun Arsenal ni won fun ni Agbaboolu Omode ti o dan ga jiya julo ni odun 2016 ti Kelechi Iheanacho ni o gba Agbaboolu ti a le foju sona fun ni odun ti o n bo.

iheanacho