Skip to content

Ojo Idije Boolu El Classico Ti Sun Siwaju

Alaga La liga, Javier Tebas ti so wipe El Classico akoko fun season 2017/2018 ti o ma waye laarin real Madrid ati Barcelona ma waye ni 23 december ni ago kan osan (1pm).  Idije boolu yi ye ko waye ni 20th December gegebi ara awon idije titele ki ilu spain to lo fun winter break.

Bi o ti se ri wipe oseese ki Real Madrid ko pa ninu idije boolu Club World Cup final ni Japan ni 17 December, won pinu lati fun real Madrid ni igba die lati sinmi.

“It will be played on Saturday 23rd at 1:00pm. That is what we have told the television companies,” Tebas told Onda Cero radio. That week, given it is Christmas time we will have a very special round of fixtures with games on Tuesday, Wednesday, Thursday, Friday and Saturday.”