Skip to content

Idi Ti Ben Bruce Fi Gbe Osuba Kare Fun DINO MELAYE Nitori Igbese Ti O Gbe Lo Si PDP

Ben Bruce Ti Gbe Osuba Kare Fun DINO MELAYE Nitori Igbese Ti O Gbe Lo Si PDP

Ogbeni Ben Bruce ti o ni ileese Silverbird ti gbe Osuba Kare fun MELAYE nitori wipe o fi egbe APC sile lo si PDP.

Lana ode oni ni Dino melaye fi egbe APC sile ninu ipade awon igbimo ile Asofin wipe egbe naa ti su oun ti o si gba aaye miran si egbe Are-Egbe naa teleri; iyen Sen. David Mark.

Ben Bruce so ni ede geesi wipe:

Great to have @dino_melaye at the @NGRSenate today and hearty welcome to our great party, @OfficialPDPNig. We will treat you good – no trauma or intimidation whatsoever.

bruce-melaye-ben-murray bruce-melaye-ben-murray bruce-melaye-ben-murray