Skip to content

Idi Ti ATIKU Fi Pada Si Egbe Oselu PDP

Idi Ti ATIKU Fi Pada Si Egbe Oselu PDP

Lati igba ti Igbakeji Are teleri naa ti fi egbe APC sile, jinnijinni ti de ba egba naa gege bi iroyin ti fiye wa wipe awon Oga agba ninu egbe na ko le dawo oro lori isele naa duro.

Bi gbogbo ihuwasi won se fihan wa, o kawon lara pupo lori iwa naa ti Atiku hu.

Eru n ba egbe APC wipe O seese ki Atiku ma fi egbe PDP di Are gege bi o ti wu lati se ni Odun 2018. Eyi ti bere lati igba ti awuye-wuye iroyin naa ti jade wipe o fe fi egbe naa sile..won si sote re titi o fi fi egbe naa sile gege bi Odigie Oyegun ti so.

Lakotan, Idi kan pataki ti ATIKU se fi egbe naa sile ni pe won le ma gbaa laaye lati dije fun ipo Are orile ede. Egbe PDP ti o ti wa teleri si gbaa towo-tese.