Skip to content

Idi Pataki Ti Ile Ejo Kotemilorun Se Gbese Le Akaanti FAYOSE

Idi Pataki Ti Ile Ejo Kotemilorun Se Gbese Le Akaanti FAYOSE

Ni Ojo’bo ni a gbo wipe Awon ile-ejo kotemilorun ti gbe’se le apo-ifowopamo (Bank Account) ti Gomina ipinle ekiti Ogbeni Ayodele Fayose.

Leyin atotonu ti adajo si da ejo re ni ile ejo kotemilorun ti ilu Ekiti ni ojo’bo wipe awon ti fi ofin de akaanti naa lori esun ti awon Ajo EFCC (Economic and Financial Crimes Commission) fi kan-an ti Adajo Justic Taiwo O. Taiwo ko da daadaa ni Ile-EJo agba ti Ijoba-apapo ni Ilu Ado-ekiti.

Gbogbo ibi ti oro naa ba ja si ni a o jabo fun-un yin.

Se Alaafia ni e wa loni????

Nje e n bawa kalo lori ero alatagba wa ti FACEBOOK, INSTAGRAM ati TWITTER @orisuntv

E dakun e ma gbagbe lati bawa pade lori awon ero naa……Tuntun: A wa lori SNAPCHAT naa