Idanileko Fun Awon Akeko Lori Lilo Egbo Igi Oloro
Ajo ti o n gbogun ti gbigbe ati lilo ogun oloro no orileede Nigeria, iyen Nation Drug Law Enforcement Agency (NDLEA) ti so wipe ki awon omo orile ede Nigeria yera fun egbo igi oloro eyi to le se ipalara fun ara won ati awon ogun ti ko ni ounte ijoba (NAFDAC number).
Iwe pelebe fun awon akeko (student handbook) ni won se afi han re.
