Ibi Ti Ileese ORISUN Ti Wa Ni Ilu Eko
Gbogbo wa ni a mo wipe laarin gbogbo Ileese telifisan kaakakiri Nigeria ati ile adulawo kaaro oojiire, Orisun l’agba.
Fun awon ti o ti n beere ibi ti ileese wa wa, a n fi asiko yii juwe ibi ti a ti n gbe da bi edun, ti a si n ro bi owe.
Ni Nomba 22, Coker Street, Ni opopo’na College Road ni Ogba ni ilu Eko.
Ni Ojoru Ikilo Jade Fun Awon Obi Lori Awon Omo Won Ni Ile-Iwe