Skip to content

Iberu-Bojo Ni Awon Argentina Yoo Fi Bawa Gba Boolu – Victor Moses

Ibere-Bojo Ni Awon Argentina Yoo Fi Bawa Gba Boolu – Victor Moses

Agbaboolu fun iko Chelsea ni oke-okun, ogbeni Victor Moses ti fiye wa wipe Orile ede Nigeria yoo ja awon Argentina laya nibi idije Group D ti won fiwon si fun FIFA world Cup RUSSIA 2018.

Iko Super Eagles yoo koju awon ti America, Iceland ati Croatia ni ibi ipele ti won fi won si. Victor Moses so wipe awon Super Eagles ko ni jawa kule nibi idije naa; iberu-bojo si ni won yoo fi bawa gba.

Fun igba kaarun ni ipele mefa final ti won ti lo, Argentina yoo ba Nigeria gba ni odun t’onbo.

Awon Agbaboolu Nla Ti O Ye Ko Lo Gba RUSSIA 2018

Laipe yii ni Nigeria na Ilu  Argentina ni ami ayo merin si meji (4-2) nibi ifesewonse ni ilu Russia. Bi Victor Moses ko se gba boolu lojo naa, o n fiye wa wipe eru n ba awon Argentina lati pade Iko Super Eagles.

RUSSIA-2018-Victor-moses-fifa-world-cup

O so lede geesi wipe:

“We keep getting Argentina for some reason. We don’t want to play against Messi, but it is what it is. We’ve got to go and play our football and see what happens. “After what Iceland did last year beating England in the last 16 of the Euros, football nowadays, there’s no easy game. “Argentina are going to be scared of us as well. “Everyone at Chelsea were saying we’re going to get a thrashing and we’re not going to make it through the group stage. “Hopefully we can go out there and make the nation proud and get out of the group.”

Ko je b’oti je, nnkan ti Victor Moses so niyen.