Skip to content

Aisha Buhari Fun Omo Orukan Ogota ni Eko Ofe Ni Daura

Aya Aare Orileede Nigeria, Hajiya Aisha Buhari ti fun awon omo orukan ogota ni eko ofe ni ile iwe alakobere kan ni daura. Arabirin Buhari ti o eto eko ofe nan i daura so wipe eko ofe yi ma ka gbogbo odun mefa ti won ma fi wan i ile eko alakobere awon ti o jere eto eko ofe yi.

E TUN LE KA: Se O Leto Ki Obi Ko Omo Ni Eko Nipa Ibalopo?

Arabirin Buhari so wipe ‘It gladdens my heart to be able to give back to the people. The love and support we have received from Nigerians has been overwhelming. As a mark of my continued appreciation, this morning, I awarded 60 orphans/ less privileged children in Daura Katsina State scholarships for the duration of their primary school education , the importance of Education cannot be underestimated and it’s the best gift one can award a child’.

Hajiya Aisha Buhari tun pin oun elo ounje ti o ni apo iresi ogota (60), tomato pelebe ogota (60) ati garri ogota (60) fun obirin marun din logorun (75) ati awon ti o ni ni agbegbe naa