Skip to content

Awon Gomina Ti Apa Ila-Oorun Si Iha Guusu Ti Gbimo Lati Se Oju Ona Ti Afefe GAS Yo Maa Gba

Awon Gomina ti Ila-oorun si Iha Guusu ti bere ise lori sise Oju-ona fun Afefe GAS ti yio gba ipinle marun ti o wa ni ekun naa lati le jeki gbigbe Gaasi kakakiri le rorun, beeni ki o mu idagbasoke ba awon ipinle naa.

Ninu atejade ti Alaga egbe awon Gomina naa iyen Gomina Dave Umahi ti ipinle Ebonyi ka si eti igbo gbogbo omo-egbe naa ni ojuo Aiku; Umahi so wipe Oju Ona naa yoo gba iye 430 wiwon ese. (430KM).

O wipe egbe naa yoo baa de ibi-gongo lati b’ojuto ise naa ki o le tete pari ni kiakia.

Gege bi o ti ko ni ede geesi:

E TUN LE KA: Awon T’O n Ta Epo Petrol Ti Pariwo Wipe Awon Ko Le Ta Epo Ni 145 MO

“The forum commended the presentation on the Aba Independent Power Plant Project by Prof. Barth Nnaji and asked him to liaise with the secretariat of the forum for further implementation with the Presidency.

Gas-Plant-GAASI-South-East-Petrol

“A private business enterprise presented to the forum a lottery business proposal in the South East states. After much deliberations, the forum asked him to reach out to the respective states,” Ko je bi o ti wi.

IROYIN: #ASIRI: Awon Nnkan Ti E Ko Mo Nipa MERCY Aigbe

Gomina naa so wipe egbe naa yoo gba awon Alaga loba-loba ni ipinle maraarun naa lalejo lati fi idi alaafia lele lori oro naa.

Ogbeni Umahi so wipe, ipejopo baa n dupe fun ifowosowopo ti awon ti o wa lati awon agbegbe naa fihan ni igba ti Are teleri Dokita Alex Ekwueme ku; o tesiwaju lati so wipe irufe iwa isokan naa ni awon nilo lati gbe ekun naa siwaju.

A l’ero wipe iru ifowosowopo yii naa yi o lo kari gbogbo orile ede Nigeria ati gbogbo awon ipinle ti o wa ninu re.

E maa bawa kalo lojoojumo fun iroyin ti  j’oju ni gbese… A nife yin lori Orisun.