Skip to content

Gbenga Adeyinka Gbe Laffmattaz Lo Ilorin

Gbenga Adeyinka je aderinposhonu agba ni orile ede nigeria yi ti o ti opo eniyan lerin ti o si ti ni oruko ni inu entertainment industry. Okan ninu awon ise aderinposhonu orisirisi ti o ma n se ni Laffmattazz ti o ti pari eto lati she eleekeje re ni ilorin.

Gbenga Adeyinka da Laffmatazz sile lati gbe ere aderinposhonu kakaakiri south west nigeria ni bi odun mefa seyin , ti eyin to se keyin sele ni ilu ibadan ni easter sunday. Gbenga Adeyinka je ko ye wa pe laffmattazz ilorin yii ma sele lati fi se ajoyo odun ileya.

E TUN LE KA: Emi O Ko Orin Bu K cee O – Harrysong

Laffmatazz ma waye ni sept 3,2017 ni banquet hall, opposite government house, awon olorin ati aderinposhonu ti o ma wa nibe ni Gbenga Adeyinka 1st, Reminisce, Olu maintain, QDot, Terry Apala, Gandoki, Omobaba, DJ Incredible, DJ Banky and DJ Lollypop, Bash, Capital Femi, Dotman, Lord of Ajasa, Toqs, Sonorous, Martins,
Climax j, Wales, Peteru, Mc Ajele, Baba Alariya ati beebelo

Gbenga Adeyinka so siwaju si wipe  gomina ilu Kwara, His Excellency, Abdulfattah Ahmed ni special guest of honour ni bi ayeye na, ti  special appearances ma wa lati odo osere Femi Adebayo aka Jelili ati Toyin Abraham.