Skip to content

A TI N GBARADI FUN EUROPA LEAGUE NITORI ARSENE WENGER – IWOBI

Agbaboolu fun Orile ede Nigeria, iyen ALEX IWOBI ti so wipe awon egbe agbaboolu Arsenal ti n gbaradi fun ifesewonse EUROPA LEAGUE nitori Akonimoogba Arsene Wenger ti o fe fi egbe naa sile leyin idije naa.

Ni ose ti o koja ni won koju egbe Atletico Madrid ninu ese keji ni papa-boolu Wanda Metropolitan ni Ojobo ti ose t’okoja.

Esi ifesewonse naa jasi Ookan si Ookan bi won se figagbaga.

IJOBA Buhari Ti Pofo Leyin Gbogbo Ileri Ti O Ti Se –  Bishop Oyedepo

Ni ede oyinbo, Iwobi so wipe:

“We are really motivated – especially by what he (Wenger) has done for the club,” Iwobi told Sky Sports News.

“We are trying to make him end the season on a high. And not just for him but for ourselves as well, so we are doing our best to get the result.

“We are very confident. We were unfortunate not to get the result we wanted against them in the first leg, but we are very confident and believe we can go to the final.”

Beeni a fe ki e mo wipe egbe agbaboolu Olympic Marseille ti ilu awon Faranse (France) pelu Red Bull Salzburg ti ilu Austria yoo koju ara won ni semi-faina ti Idije naa yoo si pari ni ojo ‘kerindinlogun osu May ti a wa yii.