Skip to content

FIFA Yo Equitorial Guinea Kuro Ni 2019 Women Wrold Cup

Ajo FIFA ti yo Equitorial guinea kuro ni ibi idije 2019 world cup ni France nitoriwipe won ko agbaboolu mewa (10) ti o toju osunwon pelu iwe ayederu.Awon agbaboolu ko pa ninu idije Qualifier ni 2016 olympics fun awon obirin ni Brazil.

E TUN LE KA:Bi Mo Se Bori Lilo Ogun Oloro Ati Irewesi Okan – Toyin Abraham

FIFA tun fun ajo agbaboolu ilu won won ni fine $102,000. Equitorial Guinea ti o je olubori eemeji ko ni kopa ni ibi idije 2020 olympics and idije meji ti women’s Africa cup of nations ni 2018 ati 2020.

E TUN LE WO: